Mama Agba’s Twilight Treat by Beautiful Nubia from album Unknown
Duration : 0 minutes & 0 seconds.
Listener : 13 peoples.
Played : 16 times and counting.
Mama Agba's Twilight Treat Asin toun tokere, awon n'a jo nja o
Ija re mo wa la
Asin fi mi ni'mu je, e gba mi lowo re o
Awo mi nbe l'oja o
Olofofo ye'ra, a fe s'oro awo 2ce
Etu o si mo, ibon j'iya o gbe
Alaisi baba omo, e ma f'iya j'omo
B'ajanaku ti gborin to ko le danikan gbe'gbo
Bi o ba si t'eye ni adie bage-bage
A ns'oro lowo iwo nlu'lu ken-ken
Bi o ba si ti oba ni mba fa'lu re ya
Omo eniyan to ri mi ti o s'ariya
Bi o ba je eranko ni a si je digbolugi
Ma fe fere si mi mo, fere
Aso fere ki mo ro
Ewu fere ki mo wo
Omode yi o gboran dan?
A i fe fere loganjo
Ma fe fere si mi mo